Dino Melaye ko orin ote bu awon alatako re lori ero ayelujara instagram.

Leyin igba ti won awon omo ile igbimo asofin fi idi re mule wipe lo to ni Dino Melaye l sile iwe giga ABU Zaria, nise ni o ko orin ote lati fi bu awon alatako re ni ede Yoruba. lol. Oni ajekun iya ni o je, eni tio toni na ton dena deni, ajekun iya ni o je.

 https://www.instagram.com/p/BSJprBhA96d/

Comments