Ijamba oko ni Ipinle Delta








Gege bi atejade ti ikan ninu awon osise Gomina ipinle Delta Ossai Ovie Sucess se, ijamba oko na waye ni ojo aiku, ni opopona  Oghara, ipinle Delta. A dupe wipe emi kankan ko sonu sugbon awon eyan fi arapa lopolopo.







Atejade to se ni yi ni ede geesi;

PHOTOS OF THE ACCIDENT THAT OCCURRED THIS MORNING AT OGHARA, BY ADAGBOYERIN DELTA STATE... Thanks to the Honorable Commissioner for transport Delta state, Hon. Vincent Uduaghan for his prompt response.....as he also vowed to take responsibility for the treatment of all the victims ....information at my disposal has it that no life was lost

Comments