Mo le ni aya pupo, ko si oun to buru. lol



Orin ti arakunrin kan ti oruko re nje Emamuzo ni ilu isoko nko niyi, nigba to se igbeyawo fun awon ololufe re meji lekan soso ni opin ose to koja yi.

Comments