Omotola Jalade se ipade pelu iyawo Aare Ghana, Rebecca Addo

Iyawo Aare Ghana, Rebecca Akufo -Addo se ipade pelu gbajugbaja osere, Omotola Jalade ni Ghana. Gege bi atejade to se pelu awon oniroyin, won soro lori bi idagbasoke yo se ba igbe aye awon omo obirin ni Africa.




Atejade na re ni ede geesi;
'I was pleased to receive a courtesy call from human rights advocate and actress Omotola Jalade-Ekeinde (@realomosexy )on Thursday. During the visit, a range of topics were discussed, including the importance of visible, accessible, and positive role models for girls and young women as they make important choices for their future.  #WomenWhoInspire,' she wrote on her IG page.

Comments