Owo awon agbofinro ti ba awon odaran ti won pa osise Jumia kan ni Porthacourt.



Awon odaran kan ni adugbo Ada George ni owo awon agbofinro ti ba, leyin igba ti won fi to wwon leti wipe won pa arakunrin osise Jumia kan ti won si so sinu kanga. Isele yi sele nigba ti arakunrin na lo gbe oja fun won ni ile, eyi to ye ki won fi san owo fun ko si ma ba ti e lo, ni se ni won pa ti won si so sinu koto.

Comments