Pope Francis lo se abewo si ilu Ejipiti (Egypt)



Pope Francis lo se abewo si ilu Egypt fun ojo meji lati petu si aawo ton waye laari awon onigbagbo ati awon musulumi, O so wipe ko si bi eyan se le sin olorun ni ododo pelu iwa jagidijagan ati iwa ipaniyan. Olori orilede Ejipiti Abdel Fattah al-Sisi lo ki kabo ni papa ofurufu Cairo.

Comments