Akeko ile eko giga OOU kan so emi re nu ninu Ijamba oko.






Aare egbe National Association of Science Students (NASS), ti ile eko giga Olabisi Onabanjo, Ogbeni  Adefuwa Christopher ti so emi re nu ninu ijamba oko kan to waye ni opopona ile ife ni ipinle Osun.
Ijamba oko na sele nigba ti oko ayokele (Bus) won fori so oko ajagbe (Trailer)kan nigba ti Adefuwa ati awon akegbe re n pada lo si ile iwe won lati ori Oke Idanre ni ipinle Ondo. Adefuwa ni kan lo ku ninu ijamba oko na ti opolopo awon akegbe re si fi ara pa yana-yana.
Adura wa ni wipe ki Olorun fi oriji, ko si fun awon obi re ni agbara lati gba bo se waye. Amin.

Comments