Opolopo awon eniyan lo ti ko si pampe, nigba ti ile alaja meta kan wo lule ni opopona Daddy alaja, agbegbe Oke Arin ni Ipinle Eko ni aro oni. Awon osise Lagos state Emergency Management Agency ati awon aradugbo na ti bere ise lati lo dola emi awon to ti ko si pampe ninu ile na.
Comments
Post a Comment