Omo odun merin kan ti oruko re nje Joshia, ni oko ayokele Pathfinder kan gba ni opopona Julius Berger ti Sani Abacha
Expressway ni ijoba ipinle Ekeremor ni ipinle Bayelsa. Iwadi ati iroyin fi to wa leti wipe ibi ayeye odun ajodun awon omode ati ogowere (Children's day party) ti ile ijosin RCCG ti Yenogoa gbe kale ni omo na nlo ti isele na fi sele.
Gege bi atejade ti agbenuso fun ile igbimo asofin ipinle Bayelsa ,ogbeni Isedirikonghen Ebi se, o so wipe won ti gbe omo na lo si ile iwosan ti itoju to peye si ti bere lori omo na. Adura wa ni wipe ki olorun fun omo na ni okun ati alfia to peye.

Comments
Post a Comment