Oludasile ati alakoso ile ise Playboy Ogbeni Hugh Hefner ti ku.

Ogbeni Hugh Hefner eni to je oludasile ile ise Playboy lo ti ku ni omo odunkanleladoorun (91years).
 O ku ninu ile re ni aarin awon molebi re. Omo merin ni ologbe na bi ki olojo to de.
    Adura wa ni wipe ki olorun te si afefe ire amin.

Comments