Eto isinku awon ogofa eniyan (120people) ti awon daran-daran (herdsmen) pa ni ilu Zamfara.



Gege bi atejade ti osise ajo NEMA ogbeni Waziri se, o so wipe awon Fulani daran-daran kan lo se ikolu si agbegbe kan ni ilu Zamfara ni aro kutu-kutu ojo alamisi ti won si pa ogofa eniyan. Eto isinku won lo waye ni esekese gege bi ilana awon musulumi.

Comments