Alukoro ile igbimo asofin Yakubu Dogara lo se ipade pelu Pope Francis loni ni orilede Romu.




Alukoro ile igbimo asofin Ogbeni Yakubu Dogara loni ojo ketalelogun osu kokanla lo si ilu Romu lati lo se ipade pelu Pope Fransis. Gege bi atejade ti Dogara se, o so wipe gbogbo isele ton sele ni orilede Nigeria lo ye Pope Francis yege-yege.

Atejade na ni yi ni ede geesi;
Today, I had the great honour of meeting His Holiness, Pope Francis @Pontifex. I was pleasantly surprised to find that he is well informed about happenings in Nigeria and prays for peace in the country. @CatholicNewsSvc @cnalive'

Comments