Ija be'le larin awon ore meji kan ni ilu Gusau, ipinle Zamfara. Ikan ninu awon ore meji yi lo mu obe jade to si fi gun ore re pa. Awon ti oro na se oju won so wipe ni kete ti odaran na ri pe ore ohun ti ku, o gbinyanju lati salo, sugbon awon ara adugbo mu kale, won si fa le awon agbofinro lowo.
Won ti gbe oku ologbe na lo si ile igboku si kan to wa ni ipinle na.
Comments
Post a Comment