Chinonso, iyawo ologbe Eric Arubayi n se iranti oko re loni ojo ketalelogun osu kokanla. (23rd Nov).
Chinonso Iyawo ologbe akorin emi Eric Arubayi, eni to ku ni nkan bi osu melokan seyin lon se iranti ololufe re loni ojo ketalelogun osu kokanla, eni ojo to ye ko je ayajo ojo igbeyawo won.
Arabirin na ninu atejade ati afihan aworan kan to fi si ori ero ayelujara instagram lo fi ibanuje re han, to si pinu lati nife oko re titi ayeraye.
Comments
Post a Comment