Ajo EFCC ton soju ipinle Gombe mu gbajugbaja onisowo Muhammad Abubakar Mubi (MD of A.M. Global Energy), won si ti fi si ewon osu mefa. Isele na sele nigba ti ikan ninu awon olubara Abubakar be lowe lati ba ra cementi ati epo robi to-to N23.5m, sugbon Abubakar ko lati fun ni oja re.
Comments
Post a Comment