Olopa omuti kan wa oko pa arakunrin kan ni adugbo Gbagada ni ipinle Eko.





Gege bi atejade ti arakunrin Adavizealao eni ti oro na se oju re se lori ero ayelujara Facebook, o so wipe olopa kan to ti mu oti yo ni agbegbe Gbagada lo wa oko pa odomode kunrin kan. O so wipe ibanuje nla lo je nigba ti awon eyan ri wipe olopa lo se iku pa omo na.  Awon to wa ni agbegbe na nigba ti oro na sele ti wa fa olopa na le awon olopa akegbe re lowo.

Atejade ti arakunrin Adavizealao se ni yi ni ede geesi;
'The vehicle responsible for the death was driven by a drunk police man who meandered from the expressway to the service lane jumping over the median distinguishing the two lanes. The Plate number is RRS 317 LA and he has since been arrested.'

Comments