Aare Buhari ti fowosowopo pelu awon Oku meta kan lati ma dari orilede Nigeria.

Aare orilede Nigeria Muhamadu Buhari lana fowo siwe lati yan awon osise ijoba si ipo. Ninu awon ti Aare yan si ipo na, iwadi fi ye wa wipe awon meta lo je oku ninu won. Ninu awon oku na ni Senator Francis Okpozo je. Eni ti iwadi fi ye wa wipe o ti ku lati odun to koja.




Oku keji ti Aare ba fowo sowopo ni Very Rev.Father Christopher lerwua Utov. eni to ku ninu osu keta odun 2017 ati Donald Ugbaja eni to ku ni osu kokanla odun 2017.
  Opolopo awon eyan lo ti wa ke gbajari lori ero ayelujara lati bere lowo Aare wipe iru ere wo ni oku ati alaye jon se papo.




Comments