Adupe ara aburo mi tin ya. Hanan Buhari lo so be.

Hanan Buhari ikan ninu awon omo Aare Buhari tosi je egbon si Yusuf eni to ni ijamba okada ni ilu Abuja ni ojokerindinlogbon osu kejila, lana se atejade kan lori ero ayelujara instagram re wipe ara aburo ohun tin ya.

Comments