Awon aworan nibi ayeye igbeyawo omo egbe agbaboolu Super Eagles Kenneth Omeruo.



Omo egbe agbaboolu Nigeria (super eagles) Kenneth Omeruo ni ogbon ojo osu kejila, se igbeyawo pelu ololufe re Chioma Nnamani ni ipinle Enugu. Opolopo awon eyan jankan-jankan lo peju sibi ayeye igbeyawo na.

Comments