Arakunrin kan ti oruko re nje Olugbenga Jeremiah Oduwole eni ton pe ara re ni Oba Oriade ti Iranmiyi Kingdom, Adeyenmi II, ti aafin re si wa ni No 1, Palace Way, Iranmiyi Kingdom, Ogun State, ni awon agbofinro ti fi si atimole ni ipinle Eko. Gege bi iwadi, awon ara adugbo na lo pe akiyesi awon agbofinro si awon isele ton ti owo arakunrin na sele bi ipuro gba owo, jibiti, ati bebe lo.
Awon agbofinro wayi ti wa bere iwadi to peye lori oro arakunrin na.
Awon agbofinro wayi ti wa bere iwadi to peye lori oro arakunrin na.
Comments
Post a Comment