BBNaija 2018; Laarin ojo meji ti idije Big Brother Naija bere, Nina ati Miracle ti bere sini sha ara won je.


Awon oludije meji yi Nina ati Miracle ni ero mohun-maworan gbe nibi ti won tin fi enu ko ara won lenu ninu baluwe.  Ojo keji re o.

Comments