Awon Fulani daran-daran lo se ikolu si ile iwe kan ni ipinle Taraba

Iroyin fi to wa leti wipe awon Fulani daran-daran kan loni lo se ikolu si ile iwe kan ni ilu Jalingo ni ipinle Taraba nibi ti won ti yin ibon mo alufa ijo Katoliki mimo kan ti won si se opolopo awon akeko lese.
Alufa Rev. Fr. Evaristus Bassey fi idi oro yi mule ninu atejade kan to se ni ede geesi ni ori ero ayelujara whatsapp. Atejade na ni yi;
“Please Frs, pray for us. Our minor seminary in Jalingo has just been attacked by the Fulani, some students are injured, some cars destroyed, two priests beaten and one shot on the leg. They are currently receiving treatment at FMC.” Father Bassey wrote
Most of the injured students are currently receiving treatement at the Federal Medical Center in Makurdi.
This attack comes three weeks after two catholic priests and 17 parishioners were killed in a similar attack by herdsmen during an early morning mass. 

Comments