Igbakeji Aare orilede nigbakanri Atiku Abubakar ti fowosowpo pelu Gomina ipinle Ogun nigbakanri Otuba Gbenga Daniel lati gbaradi fun idibo Aare orilede ton bo ni odun 2019

Ninu atejade kan ti awon omo egbe oloselu PDP fi sowo si Gomina ipinle Ogun nigbakanri Otunba Gbenga Daniel, won fi han wipe awon ti pinu lati yan gege bi alamojuto eto idibo fun ipo Aare orilede fun eto idibo ti igbakeji Aare nigbakanri Atiku Abubakar ton bo lona ni odun 2019.

Comments