Asoju Aare Yemi Osinbajo lo se abewo si ile itaja to wo ni ilu Abuja
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Asoju Aare Yemi Osinbajo, Mohammed Bello ati, Boss Mustapha lo se abewo si ile itaja to wo pa awon eyan ni agbegbe jabi ni nkan bi ago kan abo ana. O ba won kedun, o si ki awon to gbiyanju lati ran awon to wa ninu awoku ile na ku akitiyan.
Comments
Post a Comment