Owo awon agbofinro ton soju ipinle Kogi ti mu arakunrin kan ti oruko re n je Yusuf fun esun ipaniyan. Iwadi fi ye wa wipe Yusuf fi igo gun akegbe re kan ti oruko re n je Sherif pa nibi ayeye ojo ibi re pa. Awon ti oro na seoju won so wipe, ija bele laarin Yusuf ati ore re kan, Sherif si gbiyanju lati bawon yanju ija na, sugbon nise ni Yusuf gun Sherif pelu igo titi ti emi fi bo lenu re.
Awon agbofinro ti wa gbe Yusuf si ago won, won si ti pinu lati gbe lo foju ba ile ejo.
Awon agbofinro ti wa gbe Yusuf si ago won, won si ti pinu lati gbe lo foju ba ile ejo.
Comments
Post a Comment