Awon akeko ile iwe giga Federal University of Agriculture merin lo ti so emi won nu ninu ijamba oko to sele ni ipinle Benue +18





O




Ijamba oko kan to sele ni ile eko giga Federal University of Agriculture, Makurdi, ipinle Benueni awon akeko merin ti so emi won nu. Awon ti oro na se oju won lo so wipe nkan bi ago mejo aro ni isele na sele nigba ti okada kan jana mo oko akero kan lenu, ti awako na si duro lojiji, eleyi lo fa ti oko na fi gbe okiti, ti awon eyan merin si ku, ti opolopo awon miran si farapa.
Won ti wa gbe oku awon to so emi won nu lo si ite igbokusi to wa ni ile iwosan ijoba to wa ni ipinle na.

Comments