Awon asoju ile igbimo asofin se ipade pelu ajo INEC lori eto idibo odun 2019

Awon asoju ile igbimo asofin ton mojuto eto idibo loni se ipade pelu awon osise ajo INEC. Koko ipade na da lori bi eto idibo odun 2019 o se lo pelu alafia ati wipe bawo ni won o se na owo ti won ti bere lati gba fun eto idibo na.
Arabirin Aisha Dukku lo dari ipade na, ti awon agba osise ajo INEC bi Prof. Mahmoud Yakubu si peju sibi ipade na.

Comments