Egbe eleran; Miyetti Allah Cattle Breeders Association ti pase fun Saraki lati kuro lori aga gege bi Aare Ile igbimo asofin

Egbe awon eleran ati oni malu Miyetti Allah Cattle Breeders Association (MACBAN) ti pase fun aare ile igbimo asofin lati kuro lori alefa, won so wipe bi o ba ko lati se be, awon o gbe jade pelu gbogbo agbara won.

Atejade yi waye nigba ti oga egbe na ogbeni Garus Gololo n ba awon akoroyin Punch soro ni ipinle Benue. O so siwaju si wipe awon ti darapo pelu egbe oloselu APC ati ogbeni Adams Oshiomole lati le Saraki kuro lori oye.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

 “It is on this note that we are saying that Saraki ought not to be in office again as Senate President. More so, Saraki has failed to coordinate and organise the National Assembly to offer quality legislations that Nigerians need. Nigerians are in dire need of people that have the interest of the masses. Miyetti Allah is looking for a leader that would preside over the affairs of the Senate with ultimate respect for the executive and the judiciary, not someone like Senator Saraki that would always scheme to outdo the Presidency. We are now tired of Saraki’s style of leadership at the National Assembly. Therefore, we are now warning him to honourably resign his position as president of the Senate or we will force him''

Comments