Arakunrin akoroyin to wa ni atimole awon olopa lati ojo kerinla osu kejo ni ile ejo ti pase wipe ki won tu sile loni. Adajo agba Abdulwahab Mohammed ti ile ejo Kubwa Grade 1 Magistrate Court Kubwa ni ilu Abuja lo da ejo na leyin igba to gbo atotonu awon agbejoro.
Ile ejo na pase fun Samuel Ogundipe lati san owo itanran toto N500,000 ko si wa oluduro ti ko jiba si ile ejo na.
Ile ejo na pase fun Samuel Ogundipe lati san owo itanran toto N500,000 ko si wa oluduro ti ko jiba si ile ejo na.
Comments
Post a Comment