Opolopo awon eyan ni iroyin fi to wa leti wipe won ti so emi won ninu ile itaja kan to wo ni agbegbe Jabi ni ilu Abuja. Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won so, won ni nkan bi ago kan abo osan ni isele na sele.
Won so siwaju si wipe awon eyan mejo ni awon osise ajo Fire Service and National Emergency Management Authority (NEMA) ti gbe jade ninu isele na, ti gbogbo won si farapa yana-yana. Iwadi ti wa bere lori idi ti isele buruku na fi sele.
Comments
Post a Comment