Ilu mi ti-ti nigba ti adari orilede U.K arabirin Theresa May de orilede Nigeria fun abewo



Adari orilede U.K arabirin Theresa May loni de orilede Nigeria lati se awewo ranpe. Aare Muhamamdu Buhari ati awon emewa re lo peju si papko ofurufu lati ki ku abo. Arabirin May ati Aare Buhari bakana se ipade ranpe ni ile ijoba to wa ni Aso Rock ni ilu Abuja, leyin eyi ni Arabirin Theresa May gba ilu eko lo lati lo se abewo si ipinle na ati Gomina ipinle Eko, Akinwomi Ambode.

Awon aworan na ni yi;











Comments