Odomode olorin Ice K ti bi omokunrin lanti-lanti

Ice K ikan ninu omo egbe olorin Arkquake se afihan aworan kan lati fi han wipe ohun ti bi omokunrin lanti-lanti ni ilu America. O dupe lowo Olorun fun ore ofe na, osi fi ife han si ololufe re.
Atejade to se ni yi;
Unto us a child is born unto us a child is Given and his name shall be called A W E S O M E .. welcome to the world Hommie Welcome to U. S. A Welcome to ICEMPIRE ...#BigBoyawesome

Comments