Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki se ipade pelu Iyiola Omisore loni ni ile Ife

Aare ile igbimo asofin, Bukola Saraki loni lo se abewo ati ipade pelu oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe egbe oloselu SDP loni ni ilu ile Ife.

Ipade na da lori bi egbe oloselu SDP o se darapo pelu egbe oloselu PDP lati fun eto idibo ton bo lona ti egbe ajo INEC ti sun siwaju si ojo ketadinlogbon osu yi.

O se afihan ipinu won lati darapo lori ero ayelujara instagramu re. Atejade na ni yi ni ede geesi;

'I thank Sen. Iyiola Omisore for the warm reception he and his people gave me and members of my entourage in Ile-Ife today. We have agreed to work together because our goals are the same. We all want good governance in Osun State.
Over the next 24 hours, we will work out the details. Our discussion will definitely be useful for the growth of democracy in our country; the development of Osun State and its people; as well as for future engagements among political players.
From now on, it will be a win-win situation for the State of the Living Spring and Nigeria, in general'.

Comments