Aare Buhari ti de orilede Faranse fun ipade alakoko Paris Peace Forum November 10, 2018 Get link Facebook Twitter Pinterest Email Other Apps Aare orilede Nigeria Muhammadu Buhari ti de orilede Faranse lati kopa nibi ipade alakoko Paris Peace Forum. Ipade na o da lori bi idagbasoke yo se wa laarin igbayegbepo ati ibasepo laarin awon Aare orilede gbogbo agbaye. Comments
Comments
Post a Comment