Odomodekunrin olorin Mr May D ti se igbeyawo pelu ololufe re ni orilede Sweden



Gbajugbaja odomode kunrin olorin takasufe, Mr May D loni ti se igbeyawo pelu ololufe re Carolina Wassmuth ni orilede Sweden loni. 

 Awon ololufe mejeji yi ti won sese bi omokunrin lanti-lanti ti won pe oruko re ni Ethan ni won fi idunu ati ayo gbe aworan ati atejade sori ero ayelujara Instagram lati fi ife han si ara won.

Atejade ti Mr May D se ni yi ;
 'OFF THE MARKET!'





Comments