Arabirin Oby Ezekwesili eni to je oludije fun ipo Aare labe egbe oloselu ACPN ti o si fi ipinu re lati kuro ninu idije fun ipo Aare orilede Nigeria ni nkan bi ose kan seyin ti kowe fi egbe na sile.
O se afihan yi lana nigba ton ba awon akoroyin soro, o si salaye awon idi ti oun fi pina lati kuro ninu idije ati egbe na. O so siwaju si wipe ko ya oun lenu bi egbe ACPN ti se fi pinu lati gbaruku ti Aare Buhari ati egbe oloselu APC lapapo.
Atejade awon oro to so ni yi ni ede geesi;

Their actions last week did not surprise me one bit. My relationship with the ACPN became problematic once they faced the reality of my modest financial means that I had transparently disclosed to them from the beginning. Their mistake was that they harboured two wrong assumptions about me.First, they assumed that I was one of those who served in government and had a stash of looted public funds hidden somewhere to expend on the elections. When they realized that was not the case, they made a second wrong assumption by believing that I would be willing to go and obtain foreign cash to prosecute my campaign.

Comments
Post a Comment