Odomodekunrin Israel Adesanya ti fi akinkanju re han nigba to na Anderson Silva ninu idije ijakadi UFC 234
Idije ijakadi UFC 234 to waye laarin odomodekunrin omo orilede Nigeria Israel Adesanya lo ti fi akinkanju re han nigba to na akegbe re Anderson Silva omobibi orilede Brazil ni Melbourne, ni orilede Australia.
Odomodekunrin na fi idunu re han, o si dupe lowo awon ololufe re fun atileyin ojojumo.Si waju si, o kan sara si akegbe re Anderson fun akititiyan re.

Comments
Post a Comment