Ijamba ina sele ni ile ise INEC to wa ni ijoba ipinle Quan Pan ni ipinle Plateau nibi ti opolopo Dukia bi kaadi idibo, oruko awon oludibo ati gbogbo nkan to je mo eto idibo ton bo ni ose ton bo ni o ti jona ninu ijamba ina na.
Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won so, won so wipe nkan bi aago mejo ale ni ijamba ina na bere, ti o si jo di ago mejila abo oru..
Iwadi to peye ti bere lori idi ti ijamba ina na fi waye.

Comments
Post a Comment