Atejade oruko awon olukopa ninu idije BIG BROTHER NAIJA ipele kerin #ALATARODO



Leyin atotonu olojo pipe lori ijo ti idije BigBrother Naija o bere, idije na ti bere ni ale oni ogbon ojo osu kefa odun 2019.

Oruko awon oludije ti won ri aye wo inu idije na ni yi;

Charles (32years)
Emeka (33years
 Nkeiru (23years)
Precious (23years)
 Onyeka(24yrs)
Moshood(26yrs)
 Todum(32)
 Ifeanyi(23yrs)
 Oluwasegun (30yrs)
 Samson(25yrs)

Comments