Odún mewa péré ló kù tí ilé ayé o fi paré – Paito Chris Oyakhilome lo sobe

 



Ojise olorun ati oludasile ijo Christ Embassy, Paito Chris Oyakhilome ninu iwasu re kan lo ti fi idi re mule wipe laarin odun mewa ton bo yi ni ile aye o pare. 

Ninu iwasu re na, o ro gbogbo awon ti ko ba ti fi aye won fun Jesu ki won tete nitoriwipe ola le peju, paapa julo nitoripe, opin aye la wa, o si ku di e ki aye o fi pare.


Atejade na niyi ni ede geesi;

 the Rapture doesn't happen in 3 years, it might be 6 years. If it doesn't happen by then, it cannot exceed 10 years...says Pastor Chris Oyakhilome 

You have to give your heart to Jesus today because we are living in the LAST HOURS. Send us a DM and we will lead you to christ.

 

 

Comments