Olori Ooni nigbakan ri Zainabu lo se abewo si Dele Momodu nile lati jo fi oro jomitoro oro.Leyin eyi ni Dele Momodu gbe aworan awon mejeji si ori ero ayelujara instagram to si se atejade lati ki arabirin na ku ifarada ati iroju.
Atejade na ni yi ni ede geesi;
"Your Majesty,
BLESSED ARE THE PEACE MAKERS...
Thanks for the honour of pouring out your immediate and future plans to me.
Thanks for vowing not to direspect the revered throne of Oduduwa, the progenitor of the Yoruba race.
When marriages break up, it comes with painful stress and traumatic strain.
The pressure can be lessened by staying positive.
It shall be well with you..."
Comments
Post a Comment