Odomodekunrin agbaboolu Ahmed Musa loni, se iranti odun kan ti iya re fi aye sile


Gbajugbaja odomodekunrin agbaboolu Ahmed Musa ninu atejade kan to se lori ero ayelujara instagram lo kan sara si ya re, to si ki wipe o digba o se nigba ton se iranti re leyin odun kan ti iya na fi ile se aso ibora.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

"Dearest mum, I can't believe it's been 365 days without you. Not a single day goes by without thoughts of you flooding my mind. Its hard without you but I know you are in a better place. I am doing all I can to make you proud and I know you are smiling down on me. 

"Rest well mum until we meet to part no more. Amen."







Comments