Marun ninu awon omo Nigeria to rin irin ajo Hajj lo si orilede Saudi Arabia ni won ti so emi won nu.
Gege bi atejade ti alaga egbe awon onirin ajo Hajj National Hajj Commission of Nigeria, NAHCON, Abdullahi Mohammed, se, o so wipe awon omo Nigeria marun lo ti so emi won nu ni orilede Saudi Arabia.
O so siwaju si wipe awon o le se afihan oruko awon ologbe na fun awon oni iwe iroyin, sugbon lai pe, awon o so fun awon molebi won.
O so siwaju si wipe awon o le se afihan oruko awon ologbe na fun awon oni iwe iroyin, sugbon lai pe, awon o so fun awon molebi won.
Comments
Post a Comment