Ori ko egbon gomina ipinle Ekiti, Ayodele Fayose yo ninu ewo ijamba oko ni opopona Abuja si Ekiti.


Otunba Emmanuel Fayose egbon gomina ipinle Ekiti Ayodele Fayosse ni olorunko yo ninu ewu ijamba oko to waye ni opopona Abuja si Ekiti ni ojo karundinlogun osu yi nigba ti arakunrin na nlo fun ayeye ifinijoye aburo re. Gomina Ayodele Fayose lo je oye ni ilu Udiroko ni ipinle Ekiti.

Atejade ti Otunba Emmanuel Fayose se ni yi ni ede geesi lori itakun ayelujara Facebook;
'In this season of strange occurrence and politically motivated missiles we thank God for I nearly lost my brother Otunba Emmanuel Fayose in a terrible car crash on the Abuja road coming for the udiroko and chieftaincy title conferred on our brother his excellency Ayo Fayose! We remain prayerful for the lord is our only protector!  Help me to thank the lord he came out unscratched'.

Comments