Ijoba ipinle Oyo ti wo ile ise asoro-magbesi gbajugbaja olorin emi Yinka Ayefele







Ijoba ipinle Oyo ti wo Fresh Fm, ile ise asoro-magbesi ti gbajugbaja olorin emi Yinka Ayefele ko si agbegbe  Challenge si Toll Gate ni ilu Ibadan. Iwadi fi ye wa wipe ile ise na ni won wo latari wipe ori ile ijoba ni won ko si, won si ti kilo fun won tele ki won to ko ile ise na.

Ninu iforowani lenu wo kan ti Yinka Ayefele ba Punch se, o fi han wipe iwa ti ko tona ni ijoba wu latari wipe ile ise asoro-magbesi na gbiyanju lati gbe gbogbo kudie-kudie ijoba to wa lori alefa jade.O so siwaju si wipe awon tin duro de ibi ti won fe gba yo si awon, sugbon awon o mo wipe wiwo ile ise na ni won o papa se.

Atejade iwe ofin ti Ijoba ipinle Oyo fi ranse si ile ise na ni yi ni ede geesi;
''Having failed to comply with the earlier stop work/quit/ contravention notice (s) served on your development or as your structure is found to be structurally defective/poses danger or constitutes a nuisance to the occupier or the general public, you are hereby ordered to vacate the site and remove the structure thereon within three days, failure of which the government shall effect the removal and commence legal action against you in accordance with Section 43 of the law.”
an order of interlocutory injunction restraining the defendants/respondents whether by themselves, their servants, agents, privies or any person acting pursuant to the instruction of the defendants/respondents from demolishing or attempting to demolish the property of the claimants/applicants lying, being and situate at Plot 11A and 11B along link Ring Road, Lagos-Ibadan Expressway, Ibadan, Oyo State, or in any manner proceeding to enforce the notice of demolition dated August 13, 2018 with reference No. TF20181308/002, issued by the defendants/respondents pending the determination of the substantive suit already filed.”

Comments