Owo awon agbofinro ba ayederu onisegun oyinbo kan ni ipinle Osun

 Awon olopa ton soju ipinle Osun ti mu arakunrin kan omo ogbon odun ti oruko re n'je Rafiu Naheem. Owo pa Raheem ninu yara re ni Ilu Inisa, ijoba ipinle Odo otin ni ipinle Osun ni ana, ojo kokanlelogun osu kefa.

Oga olopa  Adekunle Ajisebutu nigba ton ba awon akoroyin soro fi han wipe Raheem eni ton se iwosan abele fun awon alaisan to wa ni agbegbe na ni iwadi ti fi han gege bi ayederu onisegun oyinbo.

O so siwaju si wipe opolopo awon eyan ni arakunrin na ti da emi won legbodo latari aimokan-mokan re nipa eto ilera ati eto isegun.

Atejade ti oga olopa  na se ni yi ni ede geesi;


"The suspect, a school certificate holder, who could barely speak good English, and without a formal training, had been operating an unregistered clinic in a one-bedroom mud apartment, treating unsuspecting patients of different ailments. 
When a search was conducted in his illegal 'clinic' located in a filthy environment at Inisa area, Odo Otin Local Government Area of Osun State, the following items were recovered: stethoscope, sphygmomanometer (blood pressure gauge), drips, injection and syringes, circumcision set, HCG Pregnancy Rapid Test (urine) Accurate, scalpel and other theater instruments, thermometer, analgesic and assorted drugs.
While appreciating our strategic partners, who gave the hint that led to the arrest of the suspect, the AIG Zone XI, Adeleye Oyebade, mni, urged members of the public to be wary of quacks masquerading as medical doctors, to save themselves from avoidable death.  The AIG has consequently directed that the suspect should be arraigned in court immediately without delay",









Comments