Posts

Ajo ton mojuto isesi awon Dokita ni orilede Nigeria (Nigerian Medical Association) ti pase fun won lati pada senu ise

Ijoba ipinle Akwa Ibom ti pinu lati ti awon ile iwe to wa ni ipinle na latari ajakale arun egungun COVID-19

Gbajugbaja olorin Kenny Rogers ti ku