Posts

Ekaabo si Odun tuntun, Odun 2018. Odun Isegun ati Ayo lati oke wa lo ma je fun gbogbo wa.

Aare Buhari ti fowosowopo pelu awon Oku meta kan lati ma dari orilede Nigeria.

Owo awon agbofinro ba Oba ayederu kan ni ipinle Eko.

Awako ajagbe kan wa oko pa omo ise re ni ipinle Delta. +18

Oni ni ayeye ojo ibi odunkejidinlogoji (38years) ti gbajugbaja oserekunrin Odunlade Adekola.

Awon aworan nibi ayeye igbeyawo omo egbe agbaboolu Super Eagles Kenneth Omeruo.

Owo awon agbofinro ba odaran kan nibi to tin gbiyanju lati ji batiri (battery) gbe.

Odomode kurnin kan so emi re nu ninu ijamba oko kan to sele ni opopona Benue. +18

Awon aworan nibi ayeye igbeywo Oserekunrin Ken Erics.

Oserekunrin Sadiq Daba ti pada wale leyin itoju re ni oke okun.

Adupe ara aburo mi tin ya. Hanan Buhari lo so be.

Awon agbofinro mu awon odaran ati ajinigbe lo'ju opopona Okene si Lokoja.