Posts

Ayeye Igbeyawo laarin odomode kunrin olorin Oritsefemi ati iyawo re Nabila.

Gbajugbaja onisowo Abubakar Mubi ti fi ewon osu mefa gbara fun esun jibiti.

Egbe oloselu PDP ti lo, won o si tun ni lai-lai padawa. Lai Muhammad lo so be.

Aworan Aare Buhari pelu Oba Benin Omo N'Oba Uku Akpolokpolo Ewuare II ni ilu Abuja.

Awon eyan marun o kere tan ti ku ninu ijamba oko kan to sele ni ilu Obosi, ipinle Anambra. +18

Alukoro ile igbimo asofin Yakubu Dogara lo se ipade pelu Pope Francis loni ni orilede Romu.

Chinonso, iyawo ologbe Eric Arubayi n se iranti oko re loni ojo ketalelogun osu kokanla. (23rd Nov).

Arakunrin kan gba emi ore re ni ilu Zamfara.

Ti egbe oloselu PDP o ba pada sori oye ni odun 2019, mi o ni ri orun sun. Goodluck Ebele Jonathan lo so be.

Olopa omuti kan wa oko pa arakunrin kan ni adugbo Gbagada ni ipinle Eko.

Oba Benin lo se abewo si ilu Abuja.