Posts

Oni ni ojo ibi odun kini omobirin Ogbeni Noble Igwe.

Opolopo awon eniyan farapa ninu ijamba oko kan to sele ni agbegbe Oworonshoki ni ipinle Eko.

Iya gbajugbaja olorin Olamide ti ku.

Eto isinku Ologbe Deji Tinubu.

Oserebirin Nora Nkiruka Ugo ti ku.

BBNaija 2018; Laarin ojo meji ti idije Big Brother Naija bere, Nina ati Miracle ti bere sini sha ara won je.

Ile ejo ni ilu Abuja da ejo egba fun arakunrin kan to ji apo ewa kan.

Awon omo egbe PDP ni ipinle Rivers ti fowo si ipinu Gomina Nyesom Wike lati dije fun igbakeji.

O ma se o!. Arabirin oloyun ati akeko ile iwe giga Gateway Polytechnic, Igbesa, ni ipinle Ogun so emi re nu nigba ton robi.

Igbakeji Aare Yemi Osinbajo, awon minisita ati awon Gomina lo pade oku igbakeji Aare orilede nigbakanri Alex Ekwueme ni papako ofurufu to wa ni ilu Abuja.